Close Menu
  • HOME
  • NEWS
  • POLITICS
  • SPORTS
  • ENTERTAINMENTS
  • EDUCATION
  • CRIMES
  • BUSINESS
  • OPINIONS

Subscribe to Updates

Get the latest creative news from FooBar about art, design and business.

What's Hot

Hearty Felicitations to Oba Ladoja, Olubadan Succession Process Unique – Oyo Speaker, Ogundoyin

August 20, 2025

Oyo Guber Hopeful, Dr. Adewale Kareem, Celebrates Wife Nafisat Kareem on Birthday

August 20, 2025

A Day of Double Joy: Amofin Beulah Adeoye Celebrates Life and Heritage on Isese Day

August 20, 2025
Facebook X (Twitter) Instagram
  • HOME
  • ABOUT US
  • CONTACT US
Facebook X (Twitter) Instagram Pinterest VKontakte
Heritage EchoHeritage Echo
  • HOME
  • NEWS
  • POLITICS
  • SPORTS
  • ENTERTAINMENTS
  • EDUCATION
  • CRIMES
  • BUSINESS
  • OPINIONS
Heritage EchoHeritage Echo
Home » Akojanu-Ile Igbimo Asofin Òyó, Gbenga Oyekola Ke Gbajare Si Alase Ijoba, Lati Se Idasile Ile-Iwe Alakobere ati Girama Si Awon Agbegbe ti O Nsese Dide Bo Ni Tibu-tooro Ipinle Òyó
NEWS

Akojanu-Ile Igbimo Asofin Òyó, Gbenga Oyekola Ke Gbajare Si Alase Ijoba, Lati Se Idasile Ile-Iwe Alakobere ati Girama Si Awon Agbegbe ti O Nsese Dide Bo Ni Tibu-tooro Ipinle Òyó

Opeyemi RasheedBy Opeyemi RasheedJanuary 29, 2025No Comments4 Mins Read
WhatsApp Facebook Twitter
Share
Facebook Twitter LinkedIn Pinterest Email

Akojanu-Ile Igbimo Asofin Ipinle Òyó, ti o n soji Ijoba Ibile Atiba, Asofin Gbenga Joseph Oyekola ke Gbajare Si Alase Ijoba Òyó, Lati Se Idasile Ile-Iwe Alakobere ati Girama Si Awon Agbegbe ti O Nsese Dide Bo Ni Tibu-tooro Ipinle Òyó.

Nigba ti o nse agbekale Aba ohun, ni Ile Igbimo Asofin Ipinle Òyó Loni, Asofin Gbenga Oyekola kiyesi bi awon idagba soke olokan o jokan se nde ba tibu tooro awon ijoba ibile kaakiri ipinle oyo nipase isejoba rere ti ololajulo gomina Seyi Makinde laarin odun marun seyin. Opolopo igbę loti di igboro ti oti mu ki awon adugbo titun o huyo tabi ję didasile ni gbogbo ijoba ibile wa ni ipinle yi

Adari Ile, eyin elegbemi, akitiyan ijoba lati mu aye rorun fun tolori tęlemu olugbe ipinle yi, awon olugbe ni awon agbegbe titun won yi n koju isoro aiti ma ri awon eto amaye derun ni agbegbe won. Bi apeere, ile iwe, pupo ninu awon agbegbe titun wonyi ni koni ile iwe ijoba rara, yala ti alakobere tabi girama.

Eyin elęgbę mi, ijoba gomina Seyi Makinde ko fi owo yepere mu eto eko gęgę bi opa ku tęlę fun idagbasoke.

Ti a ba woye si, igbese ijoba lati gba ogunlogo oluko si awon ile eko alakobere ati girama pelu jijina ti awon ile eko n jina si awon agbegbe titun ma le lara awon ti won ko lo si irufę awon agbegbe won yi ni bi o ti soro fun awon omo won lati ri ile eko ijoba lo. Bakanna, ni eyi tun se akoba fun eto oro aje won bi o se jepe owo goboi ni awon ti o ba da ile eko aladani ngba lowo irufe awon olugbe awon agbegbe titun wonyi atipe eni ti oba pin nu lati mu omo re lo si ille-cko ijoba, owona lori wiwo oko tabi gun alupupu lati awon agbegbe titun wonyi de ile eko ijoba naa ko tun kere rara. Awon olugbe agbegbe yi ama naa to egberun kan abo naira si egberun meji fun owo oko ile eko omo won ni ojoojumo.

Asofin Oyekola salaye wipe, ti a ba woye egberun meji ojumo lose kan, irufe eni naa yio nato egberun mewa ati ogoji egberun ni osu kan lati mu omo losi ile iwe.

Akojanu-Ile tun so wipe, akosile fi yewa pe irufe isele yi lo jeyo ni akoko ijoba oloye Bola Ige ti ijoba si pin nu lasiko na pe kı ile eko titun je didasile pelu lilo osunwon ibuso marun(5km), ibuso mewa(10k-n) fun idasile ile iwe alakobere ati girama.

Ti aba si woye lati igba naa, irufe igbese dida awon ile eko ijoba alakobere tabi girama sile koi ti waye di asiko yi. Eyin elegbe mi, awon agbegbe tuntun wonyi ko yo ijoba ibile kankan sile ni ipinle oyo. Bii apeere, agbegbe sabo ni ijoba ibile Atiba, ile eko L.A.Pry School. Sabo ni awon omo n wa lati agbegbe Elegbo, Oyo-toro, agbegbe llupeju, Temidire Sabo, ati Oroki, Olooro mogaji ni agbegbe Alayande University, Odo Ashipa, Ori-awo ni agbegbe Agunpopo ati aala ijoba ibile iwo orun Oyo (Oyo East) ati beebelo, eyi ti o to ibuso meedogun si ogun ibuso (15-20km) eyi ti o jina ju fun omode lati ma rin.

O tun gbarata pe laisi pe ijoba pese awon ohun irorun yi ni awon agbegbe tuntun wonyi oseese ki o ma se idiwo fun idagbasoke ti ijoba ni afojusun re ni awon ijoba ibile kaakiri ipinle oyo, ipese omi to jagaara, sise opopona, kiko ile iwe ati ile iwosan ni awon agbegbe tuntun wonyi yio se iranwo pupo fun igbe aye irorun ati idagbasoke eto oro aje awon irufe agbegbe titun kaakini ipinle oyo.

Tunbo kiyesi pe, fi fę si awon ijoba ibile tatari awon isodotun ti Ololajulo Gomina Seyi Makinde ti mu ba ipinle Òyó, o to, o si ye ki a gbe oriyin fun gomina ati ki a jeję atileyin ile Asofin yi si isejoba rere eleyi ti o wa nita ni ipinlę oyo bayi, se awon agba bo wonni yiniyini kenisemi.

Leyin eyin ni Asofin ti on soju Ogo-Oluwa Ati Surulere sikeji Aba you, ti Alakojanu-Ile, Ati Igbimo Asofin Ipinle Òyó pinu Lati ro eka alase Ijoba pe;

Eka-Alase ipase ile-ise eeto eko, imo ‘sayensi ati imon ero ni ipinle Oyo lati siju aanu wo awon agbegbe tuntun to sese ndide bo kaakiri Ijoba ibile ni ipinle Oyo, lori sise idasile ile eko alakobere ati girama eyi ti yio de baa awon olugbe ni awon agbegbe titun wonyi

Ro awon alaga ijoba ibile lati nawo isejoba won de awon agbegbe titun ni ijoba ibile koowa won lori pipesc awon ohun amaye derun fun awon olugbe adugbo titun wonyi

Akojanu-Ile Igbimo Asofin Òyó Ati Girama Si Awon Agbegbe ti O Nsese Dide Bo Gbenga Oyekola Heritage Echo News Heritageecho.com Ke Gbajare Si Alase Ijoba Lati Se Idasile Ile-Iwe Alakobere Ni Tibu-tooro Ipinle Òyó
Share. WhatsApp Facebook Twitter
Opeyemi Rasheed
  • Website

Related Posts

Hearty Felicitations to Oba Ladoja, Olubadan Succession Process Unique – Oyo Speaker, Ogundoyin

August 20, 2025

Oyo Guber Hopeful, Dr. Adewale Kareem, Celebrates Wife Nafisat Kareem on Birthday

August 20, 2025

A Day of Double Joy: Amofin Beulah Adeoye Celebrates Life and Heritage on Isese Day

August 20, 2025

Ido LG Chairman Joins Well-Wishers to Celebrate Lanre Sarumi

August 20, 2025
Add A Comment
Leave A Reply Cancel Reply

Recent Posts

  • Hearty Felicitations to Oba Ladoja, Olubadan Succession Process Unique – Oyo Speaker, Ogundoyin
  • Oyo Guber Hopeful, Dr. Adewale Kareem, Celebrates Wife Nafisat Kareem on Birthday
  • A Day of Double Joy: Amofin Beulah Adeoye Celebrates Life and Heritage on Isese Day
  • Ido LG Chairman Joins Well-Wishers to Celebrate Lanre Sarumi
  • Just IN: Gov Makinde Approves Ladoja’s Nomination as 44th Olubadan, Coronation Slated for Sept 26

Recent Comments

No comments to show.
Editors Picks
Top Reviews
Advertisement
Demo
Heritage Echo
Facebook X (Twitter) Instagram WhatsApp
  • HOME
  • ABOUT US
  • CONTACT US
© 2025 Heritage Echo News. Designed by SPLASH ARTS CONTACT US ON 08059330901.

Type above and press Enter to search. Press Esc to cancel.